No student devices needed. Know more
10 questions
Silebu ni ege oro ti _______ le gbe jade ni e kan soso.
emi
eran
dide
gege
Apeere oro onisilebu meji ni _______________
ijoko
amala
Oluko
jẹun
Aworan ti o so nipa oro oni silebu meji ni ____________ ?
Leta "R" duro fun __________
"My name is " tunmo si _________
Omo odun
Mo n gbe ni
Oruko mi ni
Ore mi ni
"Mo je omo odun mejo" tunmo si__________
I am 9 years old.
My school is here.
I am 8 years old
I live here.
"I live in" tunmo si
Omo dada ni mi.
Ilu mi ni....
Mo n bo.
Mo n gbe ni....
Leta alifabeeti ede Yoruba ni apapo je___________
Eefa
Ookanla
Eejila
Aarundinlogbon
"I am a Nigerian." tunmo si____
Mo je omo orile ede Naijiria.
Mo je Naira.
Owo Naira wa ni owo mi.
Mo feran Naijiria
Awon aworan wonyi so nipa oro oni silebu meji ayafi_____
Explore all questions with a free account